Ísíkẹ́lì 30:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, Èmi ti ṣe apa Fáráò Ọba Éjíbítì. A kò ì tí ì di apá náà papọ̀ láti mu kí ó san, a ko sì ti di i si àárin igi pẹlẹbẹ kí o lè ni agbára tó láti di idà mú.

Ísíkẹ́lì 30

Ísíkẹ́lì 30:12-26