Ísíkẹ́lì 30:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú ọjọ́ yóò ṣókùnkùn ní Tápárebìnígbà tí mo bá já àjàgà Éjíbítì kúrò;níbẹ̀ agbára iyì rẹ̀ yóò dópinwọn yóò fi ìkùukùu bò óàwọn abúlé rẹ ní wọn yóò lọ sí ìgbèkùn.

Ísíkẹ́lì 30

Ísíkẹ́lì 30:15-22