Ísíkẹ́lì 3:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n ìwọ, ọmọ ènìyàn, wọn yóò fi okùn dè ọ́ mọ́lẹ̀; dé ibi pé ìwọ kò ní í le rìn káàkiri láàrin àwọn ènìyàn.

Ísíkẹ́lì 3

Ísíkẹ́lì 3:23-27