Ísíkẹ́lì 3:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọwọ́ Olúwa wà lára mi níbẹ̀, ó sì wí fún mi pé, “Dìde, lọ sí ibi tí ó tẹ́jú, èmi yóò sì bá ọ sọ̀rọ̀ níbẹ̀.”

Ísíkẹ́lì 3

Ísíkẹ́lì 3:18-27