Ísíkẹ́lì 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ń sọ, kí o sì gba gbogbo ọ̀rọ̀ yìí sí ọkàn rẹ.

Ísíkẹ́lì 3

Ísíkẹ́lì 3:8-15