Ísíkẹ́lì 29:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà gbogbo àwọn olùgbé ni Ijíbítì yóò mọ pé Èmi ni Olúwa.“ ‘Ìwọ ti jẹ́ ọ̀pá ìyè fún ilé Ísírẹ́lì.

Ísíkẹ́lì 29

Ísíkẹ́lì 29:1-7