Ísíkẹ́lì 27:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìsinsìn yìí tí òkun fọ ọ túútúúnínú ibú omi;nítorí náà òwò rẹ àti gbogbo ẹgbẹ́ rẹní àárin rẹ,ni yóò ṣubú.

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:27-35