Àti nínú arò wọn ni wọn yóò sì pohùn réré ẹkún fún ọwọn yóò sì pohùnréré ẹkún sórí rẹ, wí pé:“Ta ni ó dàbí Tírèèyí tí ó parun ní àárin òkun?”