Ísíkẹ́lì 27:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Táṣíṣì ṣòwò pẹ̀lú rẹ torí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọrọ̀ tí ó ní; wọn ṣe ìpààrọ̀ fàdákà, irin tanúnganran àti òjé fún ọjà títà rẹ̀.

Ísíkẹ́lì 27

Ísíkẹ́lì 27:3-17