Ísíkẹ́lì 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì gbé ẹ̀rọ ogun tí odi rẹ, yóò sì fi ohun èlò ogun wó ilé ìṣọ́ rẹ palẹ̀.

Ísíkẹ́lì 26

Ísíkẹ́lì 26:8-14