Ísíkẹ́lì 26:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí sí Tírè: Ǹjẹ́ àwọn erékùṣù kì yóò ha wárìrì nípa ìṣubú rẹ, nígbà tí ìkórìíra ìpalára àti rírẹ́ni lọ́run bá ń sẹlẹ̀ ní inú rẹ?

Ísíkẹ́lì 26

Ísíkẹ́lì 26:5-20