Ísíkẹ́lì 25:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ ènìyàn, kọ ojú rẹ sí àwọn ará Ámónì kí ó sì sọ àṣọtẹ́lẹ̀ sí wọn.

Ísíkẹ́lì 25

Ísíkẹ́lì 25:1-3