Ísíkẹ́lì 25:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí náà báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí pé: Èmi ti ṣetán láti na ọwọ́ mi jáde sí àwọn ará Fílísítíà Èmi yóò sì ké àwọn ará Kérétì kúrò, Èmi yóò sì pa àwọn tí ó kù ní etí kún run.

Ísíkẹ́lì 25

Ísíkẹ́lì 25:7-17