Ísíkẹ́lì 24:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kó àwọn ègé ẹran tí a gé náà sínú rẹ̀,gbogbo àwọn ègé ẹran tí ó tóbi, itan àti apá.Kó àwọn egungun tí ó dára jù sínú rẹ̀

Ísíkẹ́lì 24

Ísíkẹ́lì 24:1-11