Ísíkẹ́lì 24:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹyin yóò sì ṣe bí mo ti ṣe. Ẹ̀yin kì yóò bo ìsàlẹ̀ ojú yín tàbí jẹ oúnjẹ ti àwọn tí ń sọ̀fọ̀ ń jẹ gẹ́gẹ́ bí àṣà.

Ísíkẹ́lì 24

Ísíkẹ́lì 24:19-23