Ísíkẹ́lì 23:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi yóò sì fi òpin sí ìwà ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ni ilẹ̀ náà, kí gbogbo àwọn obìnrin le gba ìkìlọ̀ kí wọn kí ó ma sì ṣe fara wé ọ.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:45-49