Ísíkẹ́lì 23:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ba sùn bí ọkùnrin ti bá aṣẹ́wó sùn, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe sùn pẹ̀lú obìnrin onífẹ̀kúfẹ̀ẹ́, Óhólà àti Óhólíbà.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:34-48