Ísíkẹ́lì 23:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí yìí ní Olúwa Olódùmarè:“Ìwọ yóò mu nínú aago ẹ̀gbọ́n rẹ,aago tí ó tóbi tí ó sì jinnú:yóò mú ìfisẹ̀sín àti ìfiṣe ẹlẹ́yà wá,nítorí tí aago náà gba nǹkan púpọ̀.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:26-37