Ísíkẹ́lì 23:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ń ṣe panṣágà ní Éjíbítì, wọn ń ṣe panṣaga láti ìgbà èwe wọn. Ní ilẹ̀ yẹn ni wọn ti fi ọwọ́ pa ọyàn wọn, níbẹ̀ ni wọn sì fọwọ́ pa igbá àyà èwe wọn.

Ísíkẹ́lì 23

Ísíkẹ́lì 23:1-6