Ísíkẹ́lì 22:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú rẹ wọn ti hùwà sí baba àti ìyá pẹ̀lú ìfojú tínrín; nínú rẹ wọn ti ni àwọn àlejò lára, wọn sì hùwà-kúwà sí aláìní baba àti opó.

Ísíkẹ́lì 22

Ísíkẹ́lì 22:6-13