Ísíkẹ́lì 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn ǹjẹ́ ìwọ yóò ha ṣe ìdájọ́ rẹ̀? Ǹjẹ́ ìwọ ha ṣe ìdájọ́ ìlú atàjẹ̀sílẹ̀? Tó bá rí bẹ́ẹ̀ dojúkọ wọn pẹ̀lú gbogbo ìwà ìríra wọn.

Ísíkẹ́lì 22

Ísíkẹ́lì 22:1-9