Ísíkẹ́lì 22:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Èmi yóò kúkú pàtẹ́wọ́ lórí èrè àìmọ̀ tí ìwọ ti jẹ, àti lórí ẹ̀jẹ̀ tí ìwọ ti ta sílẹ̀ ní àárin yín.

Ísíkẹ́lì 22

Ísíkẹ́lì 22:11-18