Ísíkẹ́lì 22:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú rẹ ọkùnrin kan ti dá ẹ̀ṣẹ̀ ìríra pẹ̀lú aya aládùúgbò rẹ̀, òmíràn bá ìyàwó ọmọ rẹ̀ ṣe, òmíràn sì bá arábìnrin rẹ̀ lòpọ̀ èyí tí í ṣe ọbàkan rẹ̀.

Ísíkẹ́lì 22

Ísíkẹ́lì 22:4-16