Ísíkẹ́lì 21:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò dàbí àmì èké sí àwọn tí ó ti búra ìtẹríba fún un, ṣùgbọ́n òun yóò ran wọn létí ẹbí wọn yóò sì mú wọn lọ sí ìgbèkùn.

Ísíkẹ́lì 21

Ísíkẹ́lì 21:18-26