Ísíkẹ́lì 20:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, dojú kọ ìhà gúsù; wàásù lòdì sí gúsù kí ìwọ sì sọtẹ́lẹ̀ sí igbó ilẹ̀ gúsù.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:42-49