Ísíkẹ́lì 20:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

N o tẹ́wọ́ gbà yín gẹ́gẹ́ bí tùràrí olóórùn dídùn nígbà tí mo ba mú yín jáde láàrin àwọn orílẹ̀ èdè tí a fọ́n yín ká sí, ń ó sì fi ìwà mímọ́ mi hàn láàrin yín lójú àwọn orilẹ̀ èdè.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:39-47