Ísíkẹ́lì 20:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo ti wà láàyè ní Olúwa Ọlọ́run wí, ń ó jọba lórí yín pẹ̀lú ọwọ́ agbára tí ń ó nà jáde pẹ̀lú ìtújáde ìbínú gbígbóná mi.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:29-37