Ísíkẹ́lì 20:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo jẹ́ kí ó sọ wọn di aláìmọ́ nípa ẹ̀bùn-nipa fífi àkọ́bí ọmọ wọn rú ẹbọ sísun àkọ́bí wọn la iná kọjá, kí ń lè kó ìpayà bá wọn, kí wọn le mọ̀ pé èmi ni Olúwa.’

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:19-32