Ísíkẹ́lì 20:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ, tẹ̀lé àṣẹ mi, kí ó sì pa òfin mi mọ́.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:11-22