Ísíkẹ́lì 20:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì fún wọn ni òfin mi, mo sì fi àwọn òfin mi hàn wọ́n; nítori pé ẹni tó bá ṣe wọ́n yóò yè nípa wọn.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:8-19