Ísíkẹ́lì 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ kẹ́wàá, oṣù kàrùn-ún ọdún keje, ní díẹ̀ nínú àwọn àgbà Ísírẹ́lì wá wádìí lọ́wọ́ Olúwa, wọn jòkòó níwájú mi.

Ísíkẹ́lì 20

Ísíkẹ́lì 20:1-7