Ísíkẹ́lì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ gbọdọ̀ sọ ọ̀rọ̀ mi fún wọn, bí wọ́n gbọ́ bí wọn kọ̀ láti gbọ́ torí pé ọlọ̀tẹ̀ ni wọ́n.

Ísíkẹ́lì 2

Ísíkẹ́lì 2:1-8