Ísíkẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ó sì tú ìwé náà fún mi. Ní ojú àti ẹ̀yìn ìwé náà ni a kọ ohùnréré ẹkún, ọ̀fọ̀ àti ègún sí.

Ísíkẹ́lì 2

Ísíkẹ́lì 2:1-10