Ísíkẹ́lì 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò ní ẹnikẹ́ni lára,ó sì sanwó fún onígbésè rẹ̀ gẹ́gẹ́bó ṣe ṣe ìlérí fún un, kò fi ipájalè ṣùgbọ́n ó fún ẹni tí ebi ńpa ní oúnjẹ, tí ó sì fi ẹ̀wù wọàwọn tí ó wà ní ìhòòhò.

Ísíkẹ́lì 18

Ísíkẹ́lì 18:4-9