Ísíkẹ́lì 18:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé inú mi kò dùn sí ikú ẹnikẹ́ni ni Olúwa Ọlọ́run wí. Nítorí náà, ẹ yípadà kí ẹ sì yè!

Ísíkẹ́lì 18

Ísíkẹ́lì 18:31-32