Ísíkẹ́lì 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí mo ti wà láàyè ni Olúwa Ọlọ́run wí, ẹ̀yin kó ni i pa òwe yìí mọ́ ni Ísírẹ́lì.

Ísíkẹ́lì 18

Ísíkẹ́lì 18:1-10