Ísíkẹ́lì 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ni àwọn talákà àti aláìní lára,ó ń fipá jalè, kì í dá padà gẹ́gẹ́ bí ìlérí,o gbójú sókè sí òrìṣà,ó sì ń ṣe ohun ìríra.

Ísíkẹ́lì 18

Ísíkẹ́lì 18:2-17