Ísíkẹ́lì 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó dàgbà, ó sì di àjàrà to kúrú ṣùgbọ́n to bolẹ̀. Àwọn ẹ̀ka rẹ̀ kọjú si i, gbòǹgbò rẹ̀ sì dúró lábẹ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni o di àjàrà ó sì mu ẹ̀ka àti ewe jáde.

Ísíkẹ́lì 17

Ísíkẹ́lì 17:2-16