Ísíkẹ́lì 17:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O gé ọ̀mùnú orí ẹ̀ka yìí kúrò, o mu un lọ sí ilẹ̀ oníṣòwò, ó sì gbìn ín sí ìlú àwọn ọlọ́jà.

Ísíkẹ́lì 17

Ísíkẹ́lì 17:1-6