Ísíkẹ́lì 17:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo igi inú oko yóò mọ̀ pé, Èmi Olúwa ni ó mú igi gíga walẹ̀, tí mo sì mú kúkurú ga sókè, tí mo mu igi tútù gbẹ, tí mo sì mú igi gbígbẹ rúwé.“ ‘Èmi Olúwa ni ó sọ bẹ́ẹ̀, Èmi yóò sì se e.’ ”

Ísíkẹ́lì 17

Ísíkẹ́lì 17:20-24