Ísíkẹ́lì 16:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò gba ẹ̀san ìwà ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àti àwọn iṣẹ́ ìríra rẹ ní Olúwa wí.

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:51-63