Ísíkẹ́lì 16:47 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í sẹ pé ìwọ rìn ni ọ̀nà wọn nìkan, tàbí ṣe àfiwé ìwà irira wọn ṣùgbọ́n ní àárin àkókò kúkúrú díẹ̀, ìwọ bàjẹ́ jù wọ́n lọ

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:44-56