Ísíkẹ́lì 16:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Gbogbo àwọn to ń pòwe, ni yóò máa pòwe yìí mọ́ ọ pé: “Bí ìyá ṣe rí, bẹ́ẹ̀ni ọmọ rẹ̀ obìnrin.”

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:41-51