Ísíkẹ́lì 16:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O ṣe àgbèrè pẹ̀lú ará Éjíbítì tí í ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ aládúgbò rẹ láti mú mi bínú pẹ̀lú ìwà àgbèrè rẹ tó ń pọ̀ sí i.

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:19-31