Ísíkẹ́lì 16:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú gbogbo iṣẹ́ ìríra àti ìwà àgbérè rẹ, o kò rántí ìgbà èwe rẹ, nígbà tó o wà ní ìhòòhò, tó ń jàgùdù nínú ẹ̀jẹ̀.

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:19-25