Ísíkẹ́lì 16:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O tún gbé oúnjẹ tí mo fún ọ-ìyẹ̀fún dáradára, òróró àti oyin-fún wọn gẹ́gẹ́ bí ẹbọ sísun olóòórùn dídùn; ohun tó ṣẹlẹ̀ nìyìí, ni Olúwa Ọlọ́run wí.

Ísíkẹ́lì 16

Ísíkẹ́lì 16:15-20