Ísíkẹ́lì 16:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá:

2. “Ọmọ ènìyàn, mú kí Jérúsálẹ́mù mọ gbogbo ìwà ìríra rẹ̀.

3. Sọ pé, ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí sí Jérúsálẹ́mù: Ìran rẹ àti ilẹ̀ ìbí rẹ wà ní ilẹ̀ Kénáànì; ará Ámórì ni baba rẹ̀, ìyá rẹ̀ sì jẹ́ ará Hítì.

Ísíkẹ́lì 16