Ísíkẹ́lì 15:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí kò bá wúlò fún nǹkankan nígbà tó wà lódidi, báwo ni yóò ṣe wá wúlò nígbà tíná ti jó o, tó sì dúdú nítorí èéfín?

Ísíkẹ́lì 15

Ísíkẹ́lì 15:1-6