Ísíkẹ́lì 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kò gòkè láti mọ odi tí ó ya ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì kí wọ́n ba lè dúró gbọin lójú ogun lọ́jọ́ Olúwa.

Ísíkẹ́lì 13

Ísíkẹ́lì 13:1-8