Ísíkẹ́lì 12:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìlú tó jẹ́ ibùgbé ènìyàn tẹ́lẹ̀ yóò di òfo, ilẹ̀ náà yóò sì di ahoro. Ẹ ó sì mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.’ ”

Ísíkẹ́lì 12

Ísíkẹ́lì 12:12-21